Fi Wọ́n Wéra: Ayé Ìsinsìnyí àti Ọjọ́ Iwájú
Àwòrán wo ló sọ bí ayé ṣe máa rí ní Párádísè?
O Tún Lè Wo
DI Ọ̀RẸ́ JÈHÓFÀ
Tẹjú Mọ́ Èrè Náà! (Orin 144)
Bó o ṣe ń kọ orin yìí, máa ronú nípa bí ayé ṣe máa dùn tó nínu Párádísè.
OHUN TÓ WÀ LÓRÍ ÌKÀNNÌ
Kẹ́kọ̀ọ́ Lára Àwọn Ọ̀rẹ́ Jèhófà—Eré
Lo àwọn eré yìí láti ṣàlàyé ohun tó ṣẹlẹ̀ nínú ọ̀wọ́ fídíò Kẹ́kọ̀ọ́ Lára Àwọn Ọ̀rẹ́ Jèhófà, kó o sì jíròrò àwọn ẹ̀kọ́ inú ẹ̀ pẹ̀lú àwọn ọmọ rẹ.
Ẹ̀KỌ́ BÍBÉLÌ
Eré Ọwọ́ fún Àwọn Ọmọdé
Lo àwọn eré ọwọ́ tó gbádùn mọ́ni tó dá lórí Bíbélì yìí láti fi kọ́ àwọn ọmọ rẹ lẹ́kọ̀ọ́ nípa ìwà rere.