Lọ wo ohun tó wà nínú rẹ̀

Lọ wo àwọn ohun tó wà

Ìwé Sámúẹ́lì Kìíní

Orí

Ohun Tó Wà Nínú Ìwé Yìí

  • 1

    • Ẹlikénà àti àwọn ìyàwó rẹ̀ (1-8)

    • Hánà tó jẹ́ àgàn gbàdúrà kó lè rọ́mọ bí (9-18)

    • Ó bí Sámúẹ́lì, ó sì fi í fún Jèhófà (19-28)

  • 2

    • Àdúrà Hánà (1-11)

    • Ẹ̀ṣẹ̀ àwọn ọmọ Élì méjèèjì (12-26)

    • Jèhófà dá ilé Élì lẹ́jọ́ (27-36)

  • 3

    • Ọlọ́run pe Sámúẹ́lì, ó sì sọ ọ́ di wòlíì (1-21)

  • 4

    • Àwọn Filísínì gba Àpótí náà (1-11)

    • Élì àti àwọn ọmọ rẹ̀ kú (12-22)

  • 5

    • Àpótí náà ní ìpínlẹ̀ àwọn Filísínì (1-12)

      • Dágónì tẹ́ (1-5)

      • Àjàkálẹ̀ àrùn kọ lu àwọn Filísínì (6-12)

  • 6

    • Àwọn Filísínì dá Àpótí náà pa dà sí Ísírẹ́lì (1-21)

  • 7

    • Àpótí náà dé Kiriati-jéárímù (1)

    • Sámúẹ́lì rọ̀ wọ́n pé: ‘Ẹ sin Jèhófà nìkan ṣoṣo’ (2-6)

    • Ísírẹ́lì ṣẹ́gun ní Mísípà (7-14)

    • Sámúẹ́lì ṣe onídàájọ́ ní Ísírẹ́lì (15-17)

  • 8

    • Ísírẹ́lì ń fẹ́ ọba (1-9)

    • Sámúẹ́lì kìlọ̀ fún àwọn èèyàn náà (10-18)

    • Jèhófà fọwọ́ sí i pé kí wọ́n ní ọba (19-22)

  • 9

    • Sámúẹ́lì pàdé Sọ́ọ̀lù (1-27)

  • 10

    • A fòróró yan Sọ́ọ̀lù ṣe ọba (1-16)

    • A fi Sọ́ọ̀lù han àwọn èèyàn náà (17-27)

  • 11

    • Sọ́ọ̀lù ṣẹ́gun àwọn ọmọ Ámónì (1-11)

    • A fìdí ipò ọba Sọ́ọ̀lù múlẹ̀ (12-15)

  • 12

    • Ọ̀rọ̀ ìdágbére Sámúẹ́lì (1-25)

      • ‘Ẹ má ṣe tẹ̀ lé àwọn ohun asán’ (21)

      • Jèhófà kò ní kọ àwọn èèyàn rẹ̀ sílẹ̀ (22)

  • 13

    • Sọ́ọ̀lù yan àwọn ọmọ ogun (1-4)

    • Sọ́ọ̀lù kọjá àyè rẹ̀ (5-9)

    • Sámúẹ́lì bá Sọ́ọ̀lù wí (10-14)

    • Ísírẹ́lì kò ní àwọn ohun ìjà (15-23)

  • 14

    • Àṣeyọrí tí Jónátánì ṣe ní Míkímáṣì (1-14)

    • Ọlọ́run lé àwọn ọ̀tá Ísírẹ́lì lọ (15-23)

    • Ẹ̀jẹ́ tí Sọ́ọ̀lù jẹ́ láìronú jinlẹ̀ (24-46)

      • Àwọn èèyàn jẹ ẹran tẹ̀jẹ̀tẹ̀jẹ̀ (32-34)

    • Àwọn ogun tí Sọ́ọ̀lù jà; ìdílé rẹ̀ (47-52)

  • 15

    • Àìgbọ́ràn mú kí Sọ́ọ̀lù dá Ágágì sí (1-9)

    • Sámúẹ́lì bá Sọ́ọ̀lù wí (10-23)

      • “Ṣíṣe ìgbọràn sàn ju ẹbọ” (22)

    • Ọlọ́run kọ Sọ́ọ̀lù lọ́ba (24-29)

    • Sámúẹ́lì pa Ágágì (30-35)

  • 16

    • Sámúẹ́lì fòróró yan Dáfídì láti jọba lẹ́yìn Sọ́ọ̀lù (1-13)

      • “Jèhófà ń rí ohun tó wà nínú ọkàn” (7)

    • Ẹ̀mí Ọlọ́run kúrò lára Sọ́ọ̀lù (14-17)

    • Dáfídì di ẹni tó ń ta háàpù fún Sọ́ọ̀lù (18-23)

  • 17

    • Dáfídì ṣẹ́gun Gòláyátì (1-58)

      • Gòláyátì pẹ̀gàn Ísírẹ́lì (8-10)

      • Dáfídì pinnu láti lọ jà (32-37)

      • Dáfídì jà ní orúkọ Jèhófà (45-47)

  • 18

    • Dáfídì àti Jónátánì di ọ̀rẹ́ (1-4)

    • Sọ́ọ̀lù ń jowú torí pé Dáfídì ń ṣẹ́gun (5-9)

    • Sọ́ọ̀lù gbìyànjú láti pa Dáfídì (10-19)

    • Dáfídì fẹ́ Míkálì ọmọ Sọ́ọ̀lù (20-30)

  • 19

    • Sọ́ọ̀lù ṣì ń kórìíra Dáfídì (1-13)

    • Dáfídì sá mọ́ Sọ́ọ̀lù lọ́wọ́ (14-24)

  • 20

    • Bí Jónátánì ṣe jẹ́ olóòótọ́ sí Dáfídì (1-42)

  • 21

    • Dáfídì jẹ búrẹ́dì àfihàn ní Nóbù (1-9)

    • Dáfídì ṣe bí ayírí ní Gátì (10-15)

  • 22

    • Dáfídì ní Ádúlámù àti Mísípè (1-5)

    • Sọ́ọ̀lù ní kí wọ́n pa àwọn àlùfáà tó wà ní Nóbù (6-19)

    • Ábíátárì sá àsálà (20-23)

  • 23

    • Dáfídì gba ìlú Kéílà sílẹ̀ (1-12)

    • Sọ́ọ̀lù lépa Dáfídì (13-15)

    • Jónátánì fún Dáfídì lókun (16-18)

    • Díẹ̀ ló kù kí ọwọ́ Sọ́ọ̀lù tẹ Dáfídì (19-29)

  • 24

    • Dáfídì dá ẹ̀mí Sọ́ọ̀lù sí (1-22)

      • Dáfídì bọ̀wọ̀ fún ẹni àmì òróró Jèhófà (6)

  • 25

    • Ikú Sámúẹ́lì (1)

    • Nábálì kan àwọn ọkùnrin Dáfídì lábùkù (2-13)

    • Ábígẹ́lì hùwà ọgbọ́n (14-35)

      • ‘Àpò ìwàláàyè lọ́dọ̀ Jèhófà’ (29)

    • Jèhófà kọ lu Nábálì tó jẹ́ òmùgọ̀ (36-38)

    • Ábígẹ́lì di ìyàwó Dáfídì (39-44)

  • 26

    • Dáfídì tún dá ẹ̀mí Sọ́ọ̀lù sí (1-25)

      • Dáfídì bọ̀wọ̀ fún ẹni àmì òróró Jèhófà (11)

  • 27

    • Àwọn Filísínì fún Dáfídì ní Síkílágì (1-12)

  • 28

    • Sọ́ọ̀lù lọ bá abẹ́mìílò ní Ẹ́ń-dórì (1-25)

  • 29

    • Àwọn Filísínì kò fọkàn tán Dáfídì (1-11)

  • 30

    • Àwọn ọmọ Ámálékì wá kó ẹrù ní Síkílágì, wọ́n sì dáná sun ún (1-6)

      • Dáfídì gba okun látọ̀dọ̀ Ọlọ́run (6)

    • Dáfídì ṣẹ́gun àwọn ọmọ Ámálékì (7-31)

      • Dáfídì gba àwọn tí wọ́n kó lẹ́rú pa dà (18, 19)

      • Ìlànà tí Dáfídì fi lélẹ̀ lórí pípín ẹrù ogun (23, 24)

  • 31

    • Ikú Sọ́ọ̀lù àti ti àwọn ọmọ rẹ̀ mẹ́ta (1-13)