YAN Ọ̀KAN Ìwé Bíbélì Jẹ́nẹ́sísì Ẹ́kísódù Léfítíkù Nọ́ńbà Diutarónómì Jóṣúà Àwọn Onídàájọ́ Rúùtù 1 Sámúẹ́lì 2 Sámúẹ́lì 1 Àwọn Ọba 2 Àwọn Ọba 1 Kíróníkà 2 Kíróníkà Ẹ́sírà Nehemáyà Ẹ́sítà Jóòbù Sáàmù Òwe Oníwàásù Orin Sólómọ́nì Àìsáyà Jeremáyà Ìdárò Ìsíkíẹ́lì Dáníẹ́lì Hósíà Jóẹ́lì Émọ́sì Ọbadáyà Jónà Míkà Náhúmù Hábákúkù Sefanáyà Hágáì Sekaráyà Málákì Mátíù Máàkù Lúùkù Jòhánù Ìṣe Róòmù 1 Kọ́ríńtì 2 Kọ́ríńtì Gálátíà Éfésù Fílípì Kólósè 1 Tẹsalóníkà 2 Tẹsalóníkà 1 Tímótì 2 Tímótì Títù Fílémónì Hébérù Jémíìsì 1 Pétérù 2 Pétérù 1 Jòhánù 2 Jòhánù 3 Jòhánù Júùdù Ìfihàn Orí 1 2 3 4 5 6 7 8 9 Ìwé Émọ́sì Orí 1 2 3 4 5 6 7 8 9 Ohun Tó Wà Nínú Ìwé Yìí 1 Émọ́sì gba iṣẹ́ kan látọ̀dọ̀ Jèhófà (1, 2) Ìdájọ́ lórí ìdìtẹ̀ tó ń wáyé (3-15) Síríà (3-5), Filísíà (6-8), Tírè (9, 10), Édómù (11, 12), Ámónì (13-15) 2 Ìdájọ́ lórí ìdìtẹ̀ tó ń wáyé (1-16) Móábù (1-3), Júdà (4, 5), Ísírẹ́lì (6-16) 3 Ìkéde ìdájọ́ Ọlọ́run (1-8) Ọlọ́run ń fi àṣírí ọ̀rọ̀ rẹ̀ hàn (7) Ohun tó máa ṣẹlẹ̀ sí Samáríà (9-15) 4 Ohun tó máa ṣẹlẹ̀ sí àwọn abo màlúù Báṣánì (1-3) Jèhófà kórìíra ìjọsìn èké Ísírẹ́lì (4, 5) Ísírẹ́lì kò gba ìbáwí (6-13) “Múra sílẹ̀ láti pàdé Ọlọ́run rẹ” (12) ‘Ọlọ́run ń sọ èrò rẹ̀ fún àwọn èèyàn’ (13) 5 Ísírẹ́lì dà bíi wúńdíá tó ṣubú (1-3) Wá Ọlọ́run, kí o lè máa wà láàyè (4-17) Kórìíra ohun búburú, nífẹ̀ẹ́ ohun rere (15) Ọjọ́ Jèhófà máa jẹ́ ọjọ́ òkùnkùn (18-27) Ọlọ́run kọ ẹbọ àwọn ọmọ Ísírẹ́lì (22) 6 Ẹ gbé! Ẹ̀yin tí ẹ kò mikàn (1-14) Ibùsùn tí wọ́n fi eyín erin ṣe; abọ́ wáìnì (4, 6) 7 Ìran tó fi hàn pé òpin Ísírẹ́lì ti sún mọ́lé (1-9) Eéṣú (1-3), iná (4-6), okùn ìwọ̀n (7-9) Wọ́n ní kí Émọ́sì má sọ tẹ́lẹ̀ mọ́ (10-17) 8 Ìran apẹ̀rẹ̀ tí èso ìgbà ẹ̀ẹ̀rùn wà nínú rẹ̀ (1-3) Ọlọ́run dẹ́bi fún àwọn aninilára (4-14) Ìyàn tẹ̀mí (11) 9 Ìdájọ́ Ọlọ́run kò ṣeé yẹ̀ sílẹ̀ (1-10) Ọlọ́run á gbé àtíbàbà Dáfídì dìde (11-15) Pa Dà Èyí Tó Kàn Tẹ̀ ẹ́ Fi ránṣẹ́ Fi ránṣẹ́ Émọ́sì—Ohun Tó Wà Nínú Ìwé Yìí BÍBÉLÌ MÍMỌ́ TI ÌTUMỌ̀ AYÉ TUNTUN (TÍ A TÚN ṢE LỌ́DÚN 2018) Émọ́sì—Ohun Tó Wà Nínú Ìwé Yìí Yorùbá Émọ́sì—Ohun Tó Wà Nínú Ìwé Yìí https://cms-imgp.jw-cdn.org/img/p/1001061100/univ/wpub/1001061100_univ_sqr_xl.jpg nwt Ámósì ojú ìwé 1240-1241