Lọ wo ohun tó wà nínú rẹ̀

Lọ wo àwọn ohun tó wà

Ìwé Náhúmù

Orí

1 2 3

Ohun Tó Wà Nínú Ìwé Yìí

  • 1

    • Ọlọ́run máa gbẹ̀san lára àwọn ọ̀tá rẹ̀ (1-7)

      • Ọlọ́run fẹ́ kí a máa jọ́sìn òun nìkan ṣoṣo (2)

      • Jèhófà mọ àwọn tó ń wá ibi ààbò lọ́dọ̀ rẹ̀ (7)

    • Nínéfè máa pa run (8-14)

      • Wàhálà kò ní dìde lẹ́ẹ̀kejì (9)

    • Ìròyìn ayọ̀ fún Júdà (15)

  • 2

    • Nínéfè máa pa run (1-13)

      • “Ilẹ̀kùn àwọn odò rẹ̀ máa ṣí sílẹ̀” (6)

  • 3

    • “Ìlú tó ń ta ẹ̀jẹ̀ sílẹ̀ gbé!” (1-19)

      • Ìdí tí Ọlọ́run fi máa dá Nínéfè lẹ́jọ́ (1-7)

      • Nínéfè máa ṣubú bíi No-ámónì (8-12)

      • Ó dájú pé Nínéfè máa ṣubú (13-19)