Lọ wo ohun tó wà nínú rẹ̀

Lọ wo àwọn ohun tó wà

Ìwé Málákì

Orí

1 2 3 4

Ohun Tó Wà Nínú Ìwé Yìí

  • 1

    • Jèhófà nífẹ̀ẹ́ àwọn èèyàn rẹ̀ (1-5)

    • Àwọn àlùfáà ń fi ẹran tó lábùkù rúbọ (6-14)

      • Wọ́n á gbé orúkọ Ọlọ́run ga láàárín àwọn orílẹ̀-èdè (11)

  • 2

    • Àwọn àlùfáà ò kọ́ àwọn èèyàn (1-9)

      • Ó yẹ kí ìmọ̀ máa wà ní ètè àwọn àlùfáà (7)

    • Àwọn èèyàn jẹ̀bi ìkọ̀sílẹ̀ tí kò tọ́ (10-17)

      • “‘Mo kórìíra ìkọ̀sílẹ̀,’ ni Jèhófà” wí (16)

  • 3

    • Olúwa tòótọ́ wá fọ tẹ́ńpìlì rẹ̀ mọ́ (1-5)

      • Ìránṣẹ́ májẹ̀mú náà (1)

    • Jèhófà rọ àwọn èèyàn pé kí wọ́n pa dà sọ́dọ̀ òun (6-12)

      • Jèhófà kì í yí pa dà (6)

      • “Ẹ pa dà sọ́dọ̀ mi, èmi yóò sì pa dà sọ́dọ̀ yín” (7)

      • ‘Ẹ mú gbogbo ìdá mẹ́wàá wá, Jèhófà yóò sì tú ìbùkún sórí yín’ (10)

    • Olódodo àti ẹni burúkú (13-18)

      • Wọ́n kọ ìwé ìrántí kan níwájú Ọlọ́run (16)

      • Ìyàtọ̀ láàárín olódodo àti ẹni burúkú (18)

  • 4

    • Èlíjà yóò wá kí ọjọ́ Jèhófà tó dé (1-6)

      • “Oòrùn òdodo yóò ràn” (2)