Lọ wo ohun tó wà nínú rẹ̀

Lọ wo àwọn ohun tó wà

Ohun Tó Wà Nínú Ìwé Gálátíà

Ohun Tó Wà Nínú Ìwé Gálátíà

Kẹ́kọ̀ọ́ nípa ohun tó jẹ́ ká mọ̀ pé Jésù Kristi àtàwọn tó máa bá a ṣàkóso ni ọmọ Ábúráhámù nípa tẹ̀mí, bó ṣe wà nínú lẹ́tà onímìísí tí Pọ́ọ̀lù kọ sáwọn ará nílùú Gálátíà.