Lọ wo ohun tó wà nínú rẹ̀

Lọ wo àwọn ohun tó wà

Ohun Tó Wà Nínú Ìwé Jémíìsì

Ohun Tó Wà Nínú Ìwé Jémíìsì

Nínú fídíò yìí, kíyè sí bí Jémíìsì ṣe lo àwọn ohun tó ṣeé fojú rí láti ṣàlàyé àwọn ẹ̀kọ́ pàtàkì tó yẹ káwa Kristẹni fi sílò.