Lọ wo ohun tó wà nínú rẹ̀

Lọ wo àwọn ohun tó wà

Ohun Tó Wà Nínú Ìwé Nọ́ńbà

Ohun Tó Wà Nínú Ìwé Nọ́ńbà

Wàá rí ìdí tó fi ṣe pàtàkì ká máa ṣègbọràn sí Jèhófà nínú gbogbo ohun tá a bá ń ṣe àti bá a ṣe lè fi hàn pé a bọ̀wọ̀ fún àwọn tó ń lò láti máa darí wa.