Lọ wo ohun tó wà nínú rẹ̀

Lọ wo àwọn ohun tó wà

Ohun Tó Wà Nínú Ìwé Sámúẹ́lì Kìíní

Ohun Tó Wà Nínú Ìwé Sámúẹ́lì Kìíní

Ìwé Sámúẹ́lì Kìíní sọ̀rọ̀ nípa ìgbà tí Jèhófà fàyè gba kí àwọn ọba máa ṣàkóso àwọn ọmọ Ísírẹ́lì dípò àwọn onídàájọ́ tó ń lò tẹ́lẹ̀.