Lọ wo ohun tó wà nínú rẹ̀

Venezuela

 

2019-06-25

VENEZUELA

Ìròyìn Láti Fẹnẹsúélà: Àwọn Ẹlẹ́rìí Jèhófà Túbọ̀ Tẹra Mọ́ Ìjọsìn Ọlọ́run Láìka Ìṣòro Sí

Bó tiẹ̀ jẹ́ pé nǹkan nira gan-an, àwọn Ẹlẹ́rìí Jèhófà ní Fẹnẹsúélà ò yéé fìgboyà wàásù.

2019-01-15

VENEZUELA

Fẹnẹsúélà: Ìgbàgbọ́ Wọn Ò Yẹ̀ Bí Nǹkan Tiẹ̀ Ń Burú Sí I

Bó tiẹ̀ jẹ́ pé ọrọ̀ ajé ò dẹrùn ní Fẹnẹsúélà, àwọn Ẹlẹ́rìí Jèhófà lórílẹ̀-èdè yìí kò dẹwọ́ lẹ́nu ìjọsìn wọn sí Ọlọ́run.

2018-02-26

VENEZUELA

Àwọn Ẹlẹ́rìí Jèhófà Lórílẹ̀-èdè Fẹnẹsúélà Ń Kọ́ Àwọn Èèyàn Lẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì Nìṣó Láìfi Ọrọ̀ Ajé Tó Dẹnu Kọlẹ̀ Pè

Inú Ìgbìmọ̀ Olùdarí Àwọn Ẹlẹ́rìí Jèhófà ò dùn rárá sí ohun tójú àwọn Ẹlẹ́rìí Jèhófà bíi tiwọn ń rí lórí ọrọ̀ ajé tó dẹnu kọlẹ̀ àti wàhálà tó ń ṣẹlẹ̀ nílùú náà.