Lọ wo ohun tó wà nínú rẹ̀

Lọ wo àwọn ohun tó wà

O Ṣé O Baba

O Ṣé O Baba

Wà á jáde:

  1. 1. Tánìíyàn bá pọ̀,

    Tọ́kàn ò sì balẹ̀,

    Ò ń gbẹ́bẹ̀ mi.

    O ṣé o Baba.

  2. 2. Tíṣòro bá dé,

    Bó ti wù kó tó,

    Ò ń gbẹ́bẹ̀ wa o,

    O ṣé o Baba.

  3. 3. A ò nídìí láti máa ṣàníyàn kankan.

    Wàá ṣọ́ ọkàn àti ìrònú wa

    Tá a bá gbẹ́kẹ̀ lé ọ pé wàá

  4. 4. Fọkàn wa balẹ̀

    Tíṣòro bá dé.

    Ò ń tọ́jú wa,

    O ṣé o Baba.

  5. 5. O kìí fàwọn olóòótọ́ sílẹ̀.

    Ò ń tọ́jú wa, O ṣé o Baba.