Atọ́ka Àwọn Àkòrí fún Jí! 2017
Jí! ni ìwé ìròyìn tó dá lórí oríṣiríṣi nǹkan tó sì délé-dóko jù lọ láyé!
Ó lé ní 360 mílíọ̀nù ẹ̀dà tá à ń tẹ̀ ní ohun tó ju ọgọ́rùn-ún èdè lọ!
ÀJỌṢE ÀWỌN ÈÈYÀN
Bó O Ṣe Lè Kọ́ Ọmọ Rẹ Ní Ẹ̀mí Ìrẹ̀lẹ̀ (ọmọ títọ́): No. 6
Bó O Ṣe Lè Mọyì Ẹnì Kejì Rẹ (ìgbéyàwó): No. 1
Ẹ̀rín Músẹ́—Ẹ̀bùn Tó O Lè Fúnni: No. 1
Iṣẹ́ Ilé Ṣe Pàtàkì (ọmọ títọ́), No. 3
Kí Làwọn Èèyàn Ń Rí Nínú Eré Tó Léwu? (àwọn ọ̀dọ́): No. 5
Nígbà Tí Àwọn Ọmọ Bá Ti Kúrò Nílé (ìgbéyàwó): No. 4
Nígbà Tí Òbí Ẹnì Kan Bá Kú (àwọn ọ̀dọ́): No. 2
‘Orúkọ Rere Dára Ju Ọ̀pọ̀ Yanturu Ọrọ̀ Lọ’: No. 4
Tí Òbí Ọmọdé Kan Bá Kú: No. 2
ÀWỌN ẸLẸ́RÌÍ JÈHÓFÀ
“Irú Ìfẹ́ Yìí Wú Wa Lórí Gan-an Ni” (ìmìtìtì ilẹ̀ lórílẹ̀-èdè Nepal): No. 1
ÀWỌN ẸNI INÚ ÌTÀN
Alhazen: No. 6
ÀWỌN ẸRANKO ÀTI EWÉKO
Ẹyẹ Arctic Tern: No. 4
Ẹ̀SÌN
Ṣé Ọ̀dọ̀ Ọlọ́run Ni Bíbélì Ti Wá Lóòótọ́? No. 3
ÌFỌ̀RỌ̀WÁNILẸ́NUWÒ
ÌLERA ÀTI ÌTỌ́JÚ
Àwọn Ọ̀dọ́ Tó Ní Ìdààmú Ọkàn: No. 1
OHUN TÓ Ń LỌ LÁYÉ
OJÚ ÌWÒYE BÍBÉLÌ
Ọ̀KAN-Ò-JỌ̀KAN