Lọ wo ohun tó wà nínú rẹ̀

Lọ wo àwọn ohun tó wà

Ṣó O Fẹ́ Kẹ́kọ̀ọ́ Sí I?

Ṣó O Fẹ́ Kẹ́kọ̀ọ́ Sí I?

Ọkùnrin ọlọ́gbọ́n kan sọ pé: “Ọgbọ́n ni ohun tó ṣe pàtàkì jù lọ, torí náà ní ọgbọ́n, pẹ̀lú gbogbo ohun tí o sì ní, ní òye.” (Òwe 4:7) Ọlọ́run máa jẹ́ ká ní ọgbọ́n àti òye tó máa jẹ́ ká lè ṣe àwọn ìpinnu tó dáa, ká sì gbádùn ayé wa.

Tó o bá fẹ́ kẹ́kọ̀ọ́ sí i nípa àwọn ìmọ̀ràn ọlọgbọ́n tó wà nínú Bíbélì, lọ sórí ìkànnì jw.org. Níbẹ̀, wàá rí . . .

  • BÍBÉLÌ

  • ÀWỌN FÍDÍÒ

  • ÀWỌN ERÉ BÈBÍ

  • ÌFỌ̀RỌ̀WÁNILẸ́NUWÒ

  • ÀWỌN ÀPILẸ̀KỌ

Ọ̀fẹ́ ni gbogbo wọn, wọ́n sì wúlò fún ọmọdé àti àgbà, ọkùnrin àti obìnrin níbi gbogbo láyé.