Re listi urun ti o winọrọn

Re listi urun ti o wi iwe we

Ẹwẹlẹ 8

Nikọ Uku Jisọs Jẹ gbẹ Rẹ Sin?

Nikọ Uku Jisọs Jẹ gbẹ Rẹ Sin?

Jisọs ka ku di ẹnẹ gba nemi kalẹ. Jọn 3:16

Ọjọ mẹẹta ti Jisọs gba ku kuro, ebirẹn bọbọ ka re eri ti a ri i ni gba ri gin eri we ṣe gboo. Jihova ji Jisọs sẹnji rẹn.

Ni ẹyin ẹrẹn, Jisọs ka mu ara ghan aghan alẹọgua ro.

Wẹrẹ rẹẹn, Jihova ka ji Jisọs sẹnji, gba sọ ọ da ẹda ẹmi areku ti o nẹ nini. Aghan olele ro ka ri i gba re ọrọn.

Oriṣẹ ka ji Jisọs sẹnji gba gba a ṣe Ọlaja Oye Oriṣẹ. Daniẹl 7:13, 14

Jisọs ka mu ẹmi ro ṣi di a gba ra irẹye ludẹ. (Matiu 20:28) Teri riraludẹ we, Oriṣẹ mu ayẹ gbẹ ẹnẹ ti ẹnẹ wa gba kalẹ gbegberegbe.

Jihova fẹsẹn Jisọs di o ṣe Ọlaja ti o wa jọba ni origho alẹ-ẹye we. Irẹye 144,000 ti o se ọlọgbarara ti a ji sẹnji kuri alẹ-ẹye we wa biri o kalẹ ni ọrọn. Jisọs biri irẹye 144,000 ghaanwe wa kolu gba ṣe udẹrini ọgbarara ni ọrọn—Oye Oriṣẹ.—Imughan 14:1-3.

Oye Oriṣẹ wa ṣe alẹ-ẹye we da paradais. Ogun, biba-ẹsije, otoku, biri ebi ee wa winọrọn juwẹrẹ. Irẹye wa ghele nẹ ọyọ.—Sam 145:16.