Lọ wo ohun tó wà nínú rẹ̀

Lọ wo àwọn ohun tó wà

Ohun Tí Mo Rò—Àkókò Tó O Fi Ń Gbádùn Ara Rẹ

Ohun Tí Mo Rò—Àkókò Tó O Fi Ń Gbádùn Ara Rẹ

APÁ 6

Ohun Tí Mo Rò​—Àkókò Tó O Fi Ń Gbádùn Ara Rẹ

Ṣàlàyé ohun tó ṣẹlẹ̀ láìpẹ́ yìí nígbà tó o tọrọ àyè lọ́wọ́ òbí rẹ pé o fẹ́ lọ gbádùn ara rẹ àmọ́ tí wọn kò fún ẹ láyè, kó o sì kọ ohun tó o rò pé ó fà á tí àwọn òbí rẹ kì í fi í gbà ẹ́ láyè nígbà míì.

․․․․․

Kọ àwọn nǹkan tó o rí kọ́ nínú apá yìí, èyí tó o lè ṣe tí àwọn òbí rẹ á fi lè túbọ̀ máa fún ẹ láyè.

․․․․․