Lọ wo ohun tó wà nínú rẹ̀

Lọ wo àwọn ohun tó wà

Èèpo Ẹ̀yìn Ìwé

Èèpo Ẹ̀yìn Ìwé

Èèpo Ẹ̀yìn Ìwé

Àkòrí àwọn apá tó wà nínú ìwé yìí ni

ÀJỌṢE RẸ NÍNÚ ÌDÍLÉ

IRÚ ÈÈYÀN TÓ O JẸ́

NÍLÉ ÌWÉ ÀTÀWỌN IBÒMÍÌ

Ọ̀RỌ̀ NÍPA ÌBÁLÒPỌ̀, ÌWÀ HÍHÙ ÀTI ÌFẸ́

ÀWỌN OHUN TÉÈYÀN FI Ń ṢE ARA RẸ̀ LÉṢE

ÀKÓKÒ TÓ O FI Ń GBÁDÙN ARA RẸ

ÌJỌSÌN RẸ

ÀFIKÚN FÚN ÀWỌN ÒBÍ

Àgbà ń kàn ẹ́ bọ̀! Báwo lo ṣe máa wá mọ àwọn ohun tí wàá fi lè máa ṣe ojúṣe rẹ nígbà tó o bá dàgbà? Ìwé Àwọn Ìbéèrè Tí Àwọn Ọ̀dọ́ Ń Béèrè​—Àwọn Ìdáhùn Tí Ó Gbéṣẹ́, Apá Kìíní yìí máa ràn ẹ́ lọ́wọ́. Inú àwọn ìlànà tó ṣeé tẹ̀ lé tó wà nínú Bíbélì la ti mú àwọn ìmọ̀ràn tó wà níbẹ̀. Ọ̀rọ̀ Ọlọ́run ti jẹ́ kí ọ̀pọ̀lọpọ̀ èèyàn mọ bí wọ́n ṣe lè yanjú àwọn ìṣòro wọn. Kà nípa bó ṣe lè ran ìwọ náà lọ́wọ́!

“Agbára láti ronú yóò máa ṣọ́ ọ, ìfòyemọ̀ yóò máa fi ìṣọ́ ṣọ́ ọ.”​—Òwe 2:11.