Lọ wo ohun tó wà nínú rẹ̀

Lọ wo àwọn ohun tó wà

Kí Ni Ìfẹ́ Tòótọ́?​—Ọ̀rọ̀ Ìbẹ̀rẹ̀

Kí Ni Ìfẹ́ Tòótọ́?​—Ọ̀rọ̀ Ìbẹ̀rẹ̀

A sọ ọ̀rọ̀ ìkìlọ̀ tó máa jẹ́ ká lè jàǹfààní nínú àwọn ìlànà tó wà nínú fídíò yìí. A tún ṣàlàyé pé ìyàtọ̀ wà nínú àwọn àṣà ìbílẹ̀ kọ̀ọ̀kan tó bá kan ọ̀ràn ìfẹ́rasọ́nà tó máa ń yọrí sí ìgbéyàwó.