Lọ wo ohun tó wà nínú rẹ̀

Ọ̀rọ̀ Pàtàkì fún Ìdílé Rẹ

Ọ̀rọ̀ Pàtàkì fún Ìdílé Rẹ

Anthony Morris III, tó jẹ́ ara Ìgbìmọ̀ Olùdarí sọ pé nǹkan míì táwọn òbí tún lè lò láti fi kọ́ àwọn ọmọ wọn lẹ́kọ̀ọ́ ni fídíò alápá púpọ̀ tí a fi àwòrán ṣe yìí.

O Tún Lè Wo

ÀWỌN FÍDÍÒ

Kẹ́kọ̀ọ́ Lára Àwọn Ọ̀rẹ́ Jèhófà

Kẹ́kọ̀ọ́ lára àwọn ọ̀rẹ́ Jèhófà tí Bíbélì sọ̀rọ̀ wọn!

Ẹ̀KỌ́ BÍBÉLÌ

Eré Ọwọ́ fún Àwọn Ọmọdé

Lo àwọn eré ọwọ́ tó gbádùn mọ́ni tó dá lórí Bíbélì yìí láti fi kọ́ àwọn ọmọ rẹ lẹ́kọ̀ọ́ nípa ìwà rere.