Lọ wo ohun tó wà nínú rẹ̀

Bá Kọ́lá Tún Ilé Ṣe!

Bá Kọ́lá Tún Ilé Ṣe!

Wa ẹ̀kọ́ yìí jáde, kí o sì bá Kọ́lá wá bèbí márùn-ún. Kọ́lá fẹ́ ṣègbọràn sí mọ́mì ẹ̀, ó fẹ́ kó àwọn bèbí ẹ̀ kúrò nílẹ̀.

O Tún Lè Wo

DI Ọ̀RẸ́ JÈHÓFÀ

Máa Wà ní Mímọ́ Tónítóní

Jèhófà ní ibi to máa ń tọ́jú àwọn nǹkan sí. Kọ́ bí o ṣe lè wà ní mímọ́ tónítóní!

OHUN TÓ WÀ LÓRÍ ÌKÀNNÌ

Kẹ́kọ̀ọ́ Lára Àwọn Ọ̀rẹ́ Jèhófà​—Eré

Lo àwọn eré yìí láti ṣàlàyé ohun tó ṣẹlẹ̀ nínú ọ̀wọ́ fídíò Kẹ́kọ̀ọ́ Lára Àwọn Ọ̀rẹ́ Jèhófà, kó o sì jíròrò àwọn ẹ̀kọ́ inú ẹ̀ pẹ̀lú àwọn ọmọ rẹ.

Ẹ̀KỌ́ BÍBÉLÌ

Eré Ọwọ́ fún Àwọn Ọmọdé

Lo àwọn eré ọwọ́ tó gbádùn mọ́ni tó dá lórí Bíbélì yìí láti fi kọ́ àwọn ọmọ rẹ lẹ́kọ̀ọ́ nípa ìwà rere.