Lọ wo ohun tó wà nínú rẹ̀

Gbàdúrà Nígbà Gbogbo: Orin àti Ọ̀rọ̀ Orin

Gbàdúrà Nígbà Gbogbo: Orin àti Ọ̀rọ̀ Orin

Wa abala orin yìí jáde, kó o sì kọrin pẹ̀lú Tósìn. Kọ́ nípa ìgbà àti ibi tí o ti lè gbàdúrà.

O Tún Lè Wo

DI Ọ̀RẸ́ JÈHÓFÀ

Gbàdúrà Nígbà Gbogbo

Fídíò tó ṣeé wà jáde yìí máa jẹ́ káwọn ọmọdé mọ ìgbà tí wọ́n lè gbàdúrà sí Jèhófà àti ibi tí wọ́n ti lè gbàdúrà.

OHUN TÓ WÀ LÓRÍ ÌKÀNNÌ

Kẹ́kọ̀ọ́ Lára Àwọn Ọ̀rẹ́ Jèhófà​—Eré

Lo àwọn eré yìí láti ṣàlàyé ohun tó ṣẹlẹ̀ nínú ọ̀wọ́ fídíò Kẹ́kọ̀ọ́ Lára Àwọn Ọ̀rẹ́ Jèhófà, kó o sì jíròrò àwọn ẹ̀kọ́ inú ẹ̀ pẹ̀lú àwọn ọmọ rẹ.

Ẹ̀KỌ́ BÍBÉLÌ

Eré Ọwọ́ fún Àwọn Ọmọdé

Lo àwọn eré ọwọ́ tó gbádùn mọ́ni tó dá lórí Bíbélì yìí láti fi kọ́ àwọn ọmọ rẹ lẹ́kọ̀ọ́ nípa ìwà rere.