Ẹ̀kọ́ 7: Máa Fúnni Kó O Lè Láyọ̀
Báwo lo ṣe lè jẹ́ aláyọ̀ bíi ti Kọ́lá?
O Tún Lè Wo
ERÉ DI Ọ̀RẸ́ JÈHÓFÀ
Máa Fúnni Kó O Lè Láyọ̀
Kọ́ àwọn ọ̀rọ̀ orin yìí kó o sì máa kọ ọ́ bó o ṣe ń wo fídíò yìí.
ERÉ DI Ọ̀RẸ́ JÈHÓFÀ
Ge Iwe To Ni Aworan Lara Yii!
Maa fi sami si ibi to o kekoo de ninu awon iwe re!
Ẹ̀KỌ́ BÍBÉLÌ
Eré Ọwọ́ fún Àwọn Ọmọdé
Lo àwọn eré ọwọ́ tó gbádùn mọ́ni tó dá lórí Bíbélì yìí láti fi kọ́ àwọn ọmọ rẹ lẹ́kọ̀ọ́ nípa ìwà rere.