Lọ wo ohun tó wà nínú rẹ̀

Ṣe Àpò Òde Ẹ̀rí Tìrẹ!

Ṣe Àpò Òde Ẹ̀rí Tìrẹ!

Wa ẹ̀kọ́ yìí jáde, tún wo fídíò náà “Jẹ́ Ká Lọ Sóde Ẹ̀rí,” kó o sì wá ṣe àpò òde ẹ̀rí tìrẹ.

O Tún Lè Wo

DI Ọ̀RẸ́ JÈHÓFÀ

Jẹ́ Ká Lọ sí Òde Ẹ̀rí

Ṣé Tósìn ti múra tán láti lọ sí òde ẹ̀rí? Wo fídíò yìí, ìwọ náà lè múra sílẹ̀ bíi ti Tósìn.

ERÉ DI Ọ̀RẸ́ JÈHÓFÀ

Àkókò Ti Tó Láti Múra!

Ṣé o lè yan aṣọ tí Kọ́lá àti Tósìn lè wọ̀ lọ sóde ẹ̀rí?

OHUN TÓ WÀ LÓRÍ ÌKÀNNÌ

Kẹ́kọ̀ọ́ Lára Àwọn Ọ̀rẹ́ Jèhófà​—Eré

Lo àwọn eré yìí láti ṣàlàyé ohun tó ṣẹlẹ̀ nínú ọ̀wọ́ fídíò Kẹ́kọ̀ọ́ Lára Àwọn Ọ̀rẹ́ Jèhófà, kó o sì jíròrò àwọn ẹ̀kọ́ inú ẹ̀ pẹ̀lú àwọn ọmọ rẹ.

Ẹ̀KỌ́ BÍBÉLÌ

Eré Ọwọ́ fún Àwọn Ọmọdé

Lo àwọn eré ọwọ́ tó gbádùn mọ́ni tó dá lórí Bíbélì yìí láti fi kọ́ àwọn ọmọ rẹ lẹ́kọ̀ọ́ nípa ìwà rere.