Ẹ Kọ́ Jòhánù 3:16 Sórí
Kọ́ ìdílé rẹ bí wọ́n ṣe máa mọ Jòhánù 3:16 sórí. Ẹ pín àwọn ọ̀rọ̀ ẹsẹ yẹn sọ láàárín ara yín léraléra títí ẹ ó fi mọ̀ ọ́n. Wa eré yìí jáde.
O Tún Lè Wo
DI Ọ̀RẸ́ JÈHÓFÀ
Ìyè Àìnípẹ̀kun Nígbẹ̀yìngbẹ́yín! (Orin 140)
Fojú inú wo ara rẹ bíi pé o wà láàyè títí láé nínú Párádísè bó o ṣe ń kọ orin yìí.
OHUN TÓ WÀ LÓRÍ ÌKÀNNÌ
Kẹ́kọ̀ọ́ Lára Àwọn Ọ̀rẹ́ Jèhófà—Eré
Lo àwọn eré yìí láti ṣàlàyé ohun tó ṣẹlẹ̀ nínú ọ̀wọ́ fídíò Kẹ́kọ̀ọ́ Lára Àwọn Ọ̀rẹ́ Jèhófà, kó o sì jíròrò àwọn ẹ̀kọ́ inú ẹ̀ pẹ̀lú àwọn ọmọ rẹ.
Ẹ̀KỌ́ BÍBÉLÌ
Eré Ọwọ́ fún Àwọn Ọmọdé
Lo àwọn eré ọwọ́ tó gbádùn mọ́ni tó dá lórí Bíbélì yìí láti fi kọ́ àwọn ọmọ rẹ lẹ́kọ̀ọ́ nípa ìwà rere.