Lọ wo ohun tó wà nínú rẹ̀

Ge Iwe To Ni Aworan Lara Yii!

Ge Iwe To Ni Aworan Lara Yii!

Gé ìwé tó ní àwòrán lára yìí, ó ń kọ́ni lẹ́kọ̀ọ́.

O Tún Lè Wo

DI Ọ̀RẸ́ JÈHÓFÀ

Gbàdúrà Nígbà Gbogbo

Fídíò tó ṣeé wà jáde yìí máa jẹ́ káwọn ọmọdé mọ ìgbà tí wọ́n lè gbàdúrà sí Jèhófà àti ibi tí wọ́n ti lè gbàdúrà.

DI Ọ̀RẸ́ JÈHÓFÀ

Olè Ò Dáa

Ojú wo ni Ọlọ́run fi ń wo olè jíjà? Ka Ẹkísódù 20:15. Wo fídíò yìí kí ìwọ àti Kọ́lá jọ kẹ́kọ̀ọ́ sí i.

DI Ọ̀RẸ́ JÈHÓFÀ

Jẹ́ Ká Lọ sí Òde Ẹ̀rí

Ṣé Tósìn ti múra tán láti lọ sí òde ẹ̀rí? Wo fídíò yìí, ìwọ náà lè múra sílẹ̀ bíi ti Tósìn.

DI Ọ̀RẸ́ JÈHÓFÀ

Ẹ Jọ̀ọ́ àti Ẹ Ṣeun

Kọ́lá ti wá rí i pé ó dára kí òun máa sọ pé ẹ jọ̀ọ́ àti ẹ ṣeun.

DI Ọ̀RẸ́ JÈHÓFÀ

Máa Fúnni Kó O Lè Láyọ̀

Ọ̀pọ̀ ọ̀nà lo lè gbà fún àwọn ẹlòmíì ní nǹkan. Ṣé o mọ ẹni tó o lè fún ní nǹkan?

DI Ọ̀RẸ́ JÈHÓFÀ

Máa Wà ní Mímọ́ Tónítóní

Jèhófà ní ibi to máa ń tọ́jú àwọn nǹkan sí. Kọ́ bí o ṣe lè wà ní mímọ́ tónítóní!