Lọ wo ohun tó wà nínú rẹ̀

Lọ wo àwọn ohun tó wà

ÀPÓTÍ Ẹ̀KỌ́ 6A

“Fá Orí Rẹ àti Irùngbọ̀n Rẹ”

“Fá Orí Rẹ àti Irùngbọ̀n Rẹ”

Ìsíkíẹ́lì ṣe àṣefihàn àwọn ohun tó máa tó ṣẹlẹ̀ ní Jerúsálẹ́mù

  • ‘Fá Orí àti Irùngbọ̀n’

    Wọ́n máa gbógun ti àwọn Júù, wọ́n sì máa pa wọ́n rẹ́

  • ‘Wọ̀n Ọ́n, Kí O sì Pín In’

    Ọlọ́run máa dìídì mú ìdájọ́ náà wá, ó sì máa délé dóko

  • ‘Sun Ún’

    Àwọn kan máa kú sínú ìlú náà

  • ‘Fi Idà Gé E’

    Wọ́n máa pa àwọn kan káàkiri ẹ̀yin odi ìlú náà

  • ‘Fọ́n Ọn Ká’

    Àwọn kan máa yè bọ́, àmọ́ ọkàn wọn ò ní balẹ̀

  • “Wé E Mọ́ Aṣọ”

    Àwọn kan máa pa dà sí Jerúsálẹ́mù láti ìgbèkùn, ìjọsìn mímọ́ ò sì ní pa run