Saturday
‘Ẹ MÁA RÌN NÍNÚ ÌFẸ́’—ÉFÉSÙ 5:2
ÒWÚRỌ̀
-
9:20 Fídíò Orin
-
9:30 Orin 85 àti Àdúrà
-
9:40 ÀPÍNSỌ ÀSỌYÉ: Máa Fi Ìfẹ́ Tí Kì Í Yẹ̀ Hàn Sáwọn
-
Tó Ń Mú Ipò Iwájú (1 Tẹsalóníkà 5:12, 13)
-
Opó Àtàwọn Ọmọ Aláìníbaba (Jémíìsì 1:27)
-
Àgbàlagbà (Léfítíkù 19:32)
-
Òjíṣẹ́ Alákòókò Kíkún (1 Tẹsalóníkà 1:3)
-
Àjèjì (Léfítíkù 19:34; Róòmù 15:7)
-
-
10:50 Orin 58 àti Ìfilọ̀
-
11:00 ÀPÍNSỌ ÀSỌYÉ: Máa Fi Ìfẹ́ Tí Kì Í Yẹ̀ Hàn Lẹ́nu Iṣẹ́ Ìwàásù
-
Fi Hàn Pé O Nífẹ̀ẹ́ Ọlọ́run (1 Jòhánù 5:3)
-
“Nífẹ̀ẹ́ Ọmọnìkejì Rẹ Bí Ara Rẹ” (Mátíù 22:39)
-
Nífẹ̀ẹ́ Ọ̀rọ̀ Jèhófà (Sáàmù 119:97; Mátíù 13:52)
-
-
11:45 ÌRÌBỌMI: Kọ́ Bó O Ṣe Lè Nífẹ̀ẹ́ Lára Jésù (Mátíù 11:28-30)
-
12:15 Orin 52 àti Àkókò Ìsinmi
Ọ̀SÁN
-
1:35 Fídíò Orin
-
1:45 Orin 84
-
1:50 ÀPÍNSỌ ÀSỌYÉ: Bí Àwọn Ará Wa Ṣe Ń Fi Ìfẹ́ Tí Kì Í Yẹ̀ Hàn ní . . .
-
Áfíríkà (Jẹ́nẹ́sísì 16:13)
-
Éṣíà (Ìṣe 2:44)
-
Yúróòpù (Jòhánù 4:35)
-
Amẹ́ríkà Ti Àríwá (1 Kọ́ríńtì 9:22)
-
Oceania (Sáàmù 35:18)
-
Amẹ́ríkà Ti Gúúsù (Ìṣe 1:8)
-
-
2:55 ÀPÍNSỌ ÀSỌYÉ: Máa Fi Ìfẹ́ Tí Kì Í Yẹ̀ Hàn Nínú Ìdílé
-
Nífẹ̀ẹ́ Ìyàwó Rẹ (Éfésù 5:28, 29)
-
Nífẹ̀ẹ́ Ọkọ Rẹ (Éfésù 5:33; 1 Pétérù 3:1-6)
-
Nífẹ̀ẹ́ Àwọn Ọmọ Rẹ (Títù 2:4)
-
-
3:35 Orin 35 àti Ìfilọ̀
-
3:45 FÍÌMÙ: Ìtàn Jòsáyà: Nífẹ̀ẹ́ Jèhófà; Kórìíra Ohun Búburú—Apá Kìíní (2 Kíróníkà 33:10-24; 34:1, 2)
-
4:15 Kọ́ Àwọn Ọmọ Rẹ Láti Máa Fi Ìfẹ́ Hàn (2 Tímótì 3:14, 15)
-
4:50 Orin 134 àti Àdúrà Ìparí