Lọ wo ohun tó wà nínú rẹ̀

Lọ wo àwọn ohun tó wà

Dáníẹ́lì Nígbàgbọ́ Jálẹ̀ Ìgbésí Ayé Rẹ̀—Apá Kejì

Dáníẹ́lì Nígbàgbọ́ Jálẹ̀ Ìgbésí Ayé Rẹ̀—Apá Kejì

Ìjọba kan tó lágbára ṣẹ́gun Bábílónì, torí náà àwọn ọ̀tá míì tún bẹ̀rẹ̀ sí í gbógun ti Dáníẹ́lì. Àwọn alátakò yìí dán ìgbàgbọ́ Dáníẹ́lì wò ju ti tẹ́lẹ̀ lọ.