Lọ wo ohun tó wà nínú rẹ̀

Lọ wo àwọn ohun tó wà

Ọ̀rẹ́

Ọ̀rẹ́

Àwọn wo ló ṣe pàtàkì jù tó yẹ ká mú lọ́rẹ̀ẹ́?

Sm 25:14; Jo 15:13-15; Jem 2:23

Tún wo Owe 3:32

  • Àpẹẹrẹ inú Bíbélì:

    • Jẹ 5:22-24—Énọ́kù sún mọ́ Ọlọ́run gan-an

    • Jẹ 6:9—Nóà náà bá Ọlọ́run rìn bíi ti baba ńlá ẹ̀, Énọ́kù

Kí nìdí tá a fi nílò àwọn ọ̀rẹ́ tòótọ́?

Owe 13:20; 17:17; 18:24; 27:17

Tún wo Owe 18:1

  • Àpẹẹrẹ inú Bíbélì:

    • Rut 1:16, 17—Rúùtù ò fi Náómì sílẹ̀ nígbà ìṣòro

    • 1Sa 18:1; 19:2, 4—Jónátánì àti Dáfídì di ọ̀rẹ́ tímọ́tímọ́

    • 2Ọb 2:2, 4, 6—Èlíṣà fi ìfẹ́ tí kì í yẹ̀ hàn sí ọ̀gá rẹ̀, wòlíì Èlíjà

Kí nìdí tó fi yẹ ká máa pé jọ déédéé pẹ̀lú àwọn tá a jọ ń sin Jèhófà?

Báwo la ṣe lè jẹ́ ọ̀rẹ́ tòótọ́, ká sì tún ní àwọn ọ̀rẹ́ tòótọ́?

Kí nìdí tó fi léwu láti máa bá àwọn tí kò nífẹ̀ẹ́ Jèhófà ṣọ̀rẹ́?

Owe 13:20; 1Kọ 15:33; Ef 5:6-9

Tún wo 1Pe 4:3-5; 1Jo 2:15-17

Tún wo “Bíbá Ayé Ṣọ̀rẹ́

  • Àpẹẹrẹ inú Bíbélì:

    • Jẹ 34:1, 2—Dínà jìyà torí pé àwọn èèyàn burúkú ló mú lọ́rẹ̀ẹ́

    • 2Kr 18:1-3; 19:1, 2—Jèhófà bá Ọba Jèhóṣáfátì wí torí pé ó bá Áhábù tó jẹ́ ọba búburú ṣọ̀rẹ́

Ṣó yẹ ká yẹra pátápátá fún àwọn tí kò sin Jèhófà?

Kí nìdí tí kò fi yẹ ká fẹ́ ẹni tí kì í ṣe Ẹlẹ́rìí Jèhófà?

Wo “Ìgbéyàwó

Kí nìdí tí kò fi yẹ ká ní ohunkóhun ṣe pẹ̀lú àwọn tí wọ́n ti yọ kúrò nínú ìjọ?