Lọ wo ohun tó wà nínú rẹ̀

Lọ wo àwọn ohun tó wà

Fífọ́nnu

Fífọ́nnu

Sm 94:4; 1Kọ 13:4; Jem 3:5, 14

Tún wo Owe 21:24; Jer 9:23, 24

  • Àpẹẹrẹ inú Bíbélì:

    • Ond 7:1-7—Jèhófà dín àwọn ọmọ ogun Gídíónì kù sí ọgọ́rùn-ún mẹ́ta (300), kó lè ṣe kedere sí wọn pé Jèhófà ló máa jẹ́ kí wọ́n ṣẹ́gun àwọn ọ̀tá wọn

    • 2Ọb 18:28-35—Senakérúbù tó jẹ́ ọba Ásíríà lo agbẹnusọ rẹ̀ láti fọ́nnu pé Jèhófà kò lè gba Jerúsálẹ́mù sílẹ̀ lọ́wọ́ Ásíríà