Lọ wo ohun tó wà nínú rẹ̀

Lọ wo àwọn ohun tó wà

Àwọn Kristẹni

Àwọn Kristẹni

Báwo ló ṣe di pé à ń pé àwọn ọmọ ẹ̀yìn Jésù ní Kristẹni?

Kí la fi ń dá àwọn Kristẹni tòótọ́ mọ̀?

Báwo ni Ọlọ́run ṣe gba àwọn Kristẹni tòótọ́ là?

Kí nìdí táwa Kristẹni fi gbà pé Kristi ni ọba wa tá a sì tún ń tẹrí ba fún un?

Kí nìdí táwa Kristẹnì tòótọ́ kì í fi í ṣe apá kan ayé?

Kí nìdí táwa Kristẹni tòótọ́ fi ń tẹ̀ lé òfin ìjọba?

Ro 13:1, 6, 7; Tit 3:1; 1Pe 2:13, 14

  • Àpẹẹrẹ inú Bíbélì:

    • Mt 22:15-22—Jésù sọ ìdí tó fi yẹ káwọn ọmọ ẹ̀yìn ẹ̀ máa san owó orí

    • Iṣe 4:19, 20; 5:27-29—Àwọn ọmọ ẹ̀yìn Jésù fi hàn pé àwọn ṣe tán láti máa tẹ̀ lé òfin ìjọba tí kò bá ṣàá ti ta ko òfin Ọlọ́run

Ọ̀nà wo làwa Kristẹni gbà jẹ́ ọmọ ogun?

Kí nìdí tó fi yẹ kí ìwà àwa Kristẹni bá ohun tá à ń kọ́ mu?

Mt 5:16; Tit 2:6-8; 1Pe 2:12

Tún wo Ef 4:17, 19-24; Jem 3:13

  • Àpẹẹrẹ inú Bíbélì:

    • Iṣe 9:1, 2; 19:9, 23—Ìgbà kan wà tí wọ́n ń pe ẹ̀sìn Kristẹni ní “Ọ̀nà Náà,” èyí jẹ́ ká rí i pé ó gbọ́dọ̀ hàn nínú gbogbo ohun tá à ń ṣe pé ọmọ ẹ̀yìn Kristi ni wá

Kí nìdí tó fi yẹ káwa Kristẹni tòótọ́ jẹ́ Ẹlẹ́rìí fún Jèhófà Ọlọ́run?

Kí nìdí tó fi yẹ káwa Kristẹni tòótọ́ tún máa jẹ́rìí nípa Jésù Kristi?

Kí nìdí tó fi yẹ kí gbogbo Kristẹni tòótọ́ máa wàásù ìhìn rere?

Ṣé ó yẹ káwa Kristẹni máa bẹ̀rù inúnibíni?

Wo “Inúnibíni

Ṣé gbogbo Kristẹni tòótọ́ ló máa lọ bá Jésù Kristi jọba lọ́run?

Ibo ni èyí tó pọ̀ jù lára àwọn Kristẹni tòótọ́ ti máa gbádùn ìyè àìnípẹ̀kun?

Ṣé a lè rí Kristẹni tòótọ́ nínú àwọn ẹ̀sìn tó ń pera wọn ní Kristẹni lónìí?

Ṣé gbogbo àwọn tó ń pera wọn ní Kristẹni ni ọmọlẹ́yìn Jésù lóòótọ́?

Mt 7:21-23; Ro 16:17, 18; 2Kọ 11:13-15; 2Pe 2:1

  • Àpẹẹrẹ inú Bíbélì:

    • Mt 13:24-30, 36-43—Jésù sọ àpéjúwe kan tó fi hàn pé àwọn ayédèrú Kristẹni máa pọ̀

    • 2Kọ 11:24-26—Àpọ́sítélì Pọ́ọ̀lù sọ pé “àwọn èké arákùnrin” wà lára àwọn tó mú kí nǹkan nira fóun

    • 1Jo 2:18, 19—Àpọ́sítélì Jòhánù kìlọ̀ pé “ọ̀pọ̀ aṣòdì sí Kristi” ló ti kúrò nínú òtítọ́