Lọ wo ohun tó wà nínú rẹ̀

Lọ wo àwọn ohun tó wà

Gbẹ́kẹ̀ Lé Jèhófà

Gbẹ́kẹ̀ Lé Jèhófà

Owe 3:5, 21-26; Ais 26:3, 4; Jer 17:7, 8

Tún wo Sm 34:8; 40:4, 5; Owe 20:22; Ais 30:15

  • Àpẹẹrẹ inú Bíbélì:

    • 1Kr 5:18-20, 22—Torí pé àwọn ọmọ Ísírẹ́lì gbẹ́kẹ̀ lé Jèhófà, wọ́n ṣẹ́gun àwọn ọ̀tá wọn

    • 2Kr 14:9-13—Nígbà táwọn ọ̀tá tó lágbára dojú kọ Ọba Ásà, ó gbàdúrà, ó sì gbẹ́kẹ̀ lé Jèhófà