Lọ wo ohun tó wà nínú rẹ̀

Lọ wo àwọn ohun tó wà

Ìtẹ́lọ́rùn

Ìtẹ́lọ́rùn

Owe 30:8, 9; 1Ti 6:6-8; Heb 13:5

Tún wo Mt 6:11, 19-21, 24-33; Iṣe 20:35; Flp 4:11-13

  • Àpẹẹrẹ inú Bíbélì:

    • 1Ọb 17:8-16—Nígbà tí Jèhófà bù kún opó Sáréfátì, dípò tí Jèhófà á fi fún un ní ohun ìní tó pọ̀, ìwọ̀nba oúnjẹ tó nílò lóòjọ́ ló pèsè fún un. Ìtàn náà jẹ́ ká rí i pé ó yẹ ká nítẹ̀ẹ́lọ́rùn