Lọ wo ohun tó wà nínú rẹ̀

Lọ wo àwọn ohun tó wà

Ìyọlẹ́gbẹ́

Ìyọlẹ́gbẹ́

Kí nìdí tó fi yẹ káwọn alàgbà máa dáàbò bo ìjọ lọ́wọ́ àwọn tó ń hùwà burúkú?

Báwo ni ìwà burúkú tí arákùnrin tàbí arábìnrin kan hù ṣe lè kó bá gbogbo ìjọ lápapọ̀?

1Kọ 5:1, 2, 5, 6

  • Àpẹẹrẹ inú Bíbélì:

    • Joṣ 7:1, 4-14, 20-26—Nígbà tí Ákánì àti ìdílé rẹ̀ hùwà burúkú, gbogbo orílẹ̀-èdè Ísírẹ́lì ló jìyà

    • Jon 1:1-16—Nígbà tí Jónà ò ṣe ohun tí Jèhófà ní kó ṣe, ó fi ẹ̀mí gbogbo àwọn tí wọ́n jọ wà nínú ọkọ̀ sínú ewu

Àwọn ìwà wo ló yẹ kẹ́nì kan sá fún tí kò bá fẹ́ kí wọ́n yọ òun kúrò nínú ìjọ Kristẹni?

Kí ló yẹ ká ṣe fún Kristẹni kan tó ń bá a lọ láti máa dá ẹ̀ṣẹ̀ tó burú gan-an?

Àwọn nǹkan wo ló yẹ káwọn alàgbà mọ̀ kí wọ́n tó ṣèpinnu nígbà tí wọ́n bá ń gbọ́ ẹjọ́ ẹnì kan?

Báwo làwọn alàgbà tó ń gbọ́ ẹjọ́ ẹnì kan ṣe máa mọ̀ pé òótọ́ lẹni náà dá ẹ̀ṣẹ̀ tó burú gan-an?

Kí nìdí tó fi máa ń pọn dandan pé kí wọ́n bá àwọn kan wí tàbí yọ wọ́n kúrò nínú ìjọ, báwo nìyẹn sì ṣe máa ṣe ìjọ láǹfààní?

Kí ni Bíbélì sọ nípa bó ṣe yẹ ká máa ṣe sáwọn tí wọ́n yọ kúrò nínú ìjọ?

Kí ló máa ṣẹlẹ̀ tí ẹni tí wọ́n yọ kúrò nínú ìjọ bá ronú pìwà dà?

Kí ni gbogbo wa lè ṣe kí ìjọ lè wà ní mímọ́?

Tẹ́rù bá tiẹ̀ ń ba ẹnì kan pé wọ́n lè yọ òun kúrò nínú ìjọ, kí nìdí tí kò fi yẹ kẹ́ni náà bo ẹ̀ṣẹ̀ tó dá mọ́lẹ̀?

Tí wọn ò bá tiẹ̀ tí ì yọ ẹnì kan tó ń hùwà tí kò bójú mu kúrò nínú ìjọ, kí nìdí tí kò fi yẹ ká máa ṣe wọléwọ̀de pẹ̀lú ẹni náà?

Kí ni Kristẹni kan lè pinnu láti ṣe tí wọ́n bá lù ú ní jìbìtì tàbí bà á lórúkọ jẹ́, kí ló sì lè mú kó pinnu láti ṣe bẹ́ẹ̀?

Tí ẹnì kan bá ń hùwà tí kò bójú mu, kí nìdí tó fi ṣe pàtàkì káwọn tí òtítọ́ jinlẹ̀ nínú wọn ran ẹni náà lọ́wọ́?