Lọ wo ohun tó wà nínú rẹ̀

Lọ wo àwọn ohun tó wà

Èso Tẹ̀mí

Èso Tẹ̀mí

Àwọn ìwà wo ni ẹ̀mí mímọ́ lè ràn wá lọ́wọ́ láti ní, kí sì nìdí tó fi yẹ ká lẹ́mìí ìrẹ̀lẹ̀ kí Ọlọ́run tó lè fún wa ní ẹ̀mí mímọ́ rẹ̀?

Ga 5:22, 23; Jem 4:6

  • Àpẹẹrẹ inú Bíbélì:

    • Sm 143:1, 4-11—Nígbà tí Ọba Dáfídì ní ìṣòro tó le gan-an, ó ronú lórí àwọn iṣẹ́ Jèhófà, ó sì bẹ Jèhófà pé kó fún òun ní ẹ̀mí mímọ́

    • Lk 11:9-13—Jésù sọ àpèjúwe kan kó lè rán wa létí pé ó wu Jèhófà láti fún wa ní ẹ̀mí mímọ́ tá a bá béèrè fún un