Lọ wo ohun tó wà nínú rẹ̀

Lọ wo àwọn ohun tó wà

Ọ̀làwọ́

Ọ̀làwọ́

Owe 11:25; Iṣe 20:35; 2Kọ 9:11

Tún wo Owe 19:17; Mt 10:8; Lk 6:38

  • Àpẹẹrẹ inú Bíbélì:

    • 1Kr 22:6-16—Ó dùn Dáfídì gan-an pé òun ò láǹfààní láti kọ́ tẹ́ńpìlì, síbẹ̀ ó fi tinútinú ṣètìlẹyìn fún iṣẹ́ kíkọ́ tẹ́ńpìlì náà

    • 1Ọb 17:8-16—Oúnjẹ díẹ̀ tí opó Sáréfátì àti ọmọ ẹ̀ máa jẹ ni wọ́n ní, síbẹ̀ opó náà fún wòlíì Èlíjà lóúnjẹ