Lọ wo ohun tó wà nínú rẹ̀

Lọ wo àwọn ohun tó wà

Àwọn Òbí Àgbà

Àwọn Òbí Àgbà
  • Àpẹẹrẹ inú Bíbélì:

    • 1Ọb 15:9-13—Kí Ọba Ásà lè fi hàn pé òun jẹ́ àdúróṣinṣin sí Jèhófà, ó fìgboyà yọ ìyá rẹ̀ àgbà kúrò ní ipò ìyá ọba

    • Owe 13:22—Táwọn òbí àgbà bá fi ìjọsìn Jèhófà sípò àkọ́kọ́, ogún tó dáa ni wọ́n ń fi sílẹ̀ yẹn

    • 2Ti 1:5; 3:14, 15—Pọ́ọ̀lù sọ ohun tó dáa nípa Lọ́ìsì ìyá ìyá Tímótì, torí pé ó ní ìgbàgbọ́ tí kò ní ẹ̀tàn àti pé ó gbìyànjú gan-an bó ṣe kọ́ Tímótì lẹ́kọ̀ọ́ òtítọ́ láti kékeré jòjòló