Lọ wo ohun tó wà nínú rẹ̀

Lọ wo àwọn ohun tó wà

Jẹ́ Olóòótọ́

Jẹ́ Olóòótọ́

Di 25:13-16; 2Kọ 8:21; Ef 4:25; Heb 13:18

Tún wo Job 6:25; Owe 3:32; 6:16-19; 2Kọ 6:3, 4, 7, 8

  • Àpẹẹrẹ inú Bíbélì:

    • Sm 15:1-5—Jèhófà sọ àwọn nǹkan tẹ́ni tó bá fẹ́ jẹ́ ọ̀rẹ́ ẹ̀ tímọ́tímọ́ gbọ́dọ̀ máa ṣe, lára ẹ̀ ni pé ẹni náà gbọ́dọ̀ jẹ́ olóòótọ́

    • Iṣe 5:1-10—Ananáyà àti Sàfírà kò sọ òótọ́, wọ́n sì jìyà ohun tí wọ́n ṣe