Lọ wo ohun tó wà nínú rẹ̀

Lọ wo àwọn ohun tó wà

Àgàbàgebè; Ẹ̀tàn

Àgàbàgebè; Ẹ̀tàn

2Kọ 6:4, 6; Jem 3:17

  • Àpẹẹrẹ inú Bíbélì:

    • Mt 23:7, 23-28—Jésù dẹ́bi fáwọn aṣáájú ẹ̀sìn torí pé ẹlẹ̀tàn ni wọ́n

    • Ga 2:11-14—Àpọ́sítélì Pọ́ọ̀lù bá àpọ́sítélì Pétérù wí torí pé ó jẹ́ alágàbàgebè