Lọ wo ohun tó wà nínú rẹ̀

Lọ wo àwọn ohun tó wà

Ìbọ̀rìṣà

Ìbọ̀rìṣà

1Kọ 5:11; 10:14; Kol 3:5

Tún wo Di 4:25, 26; Ais 42:8; 1Jo 5:21

  • Àpẹẹrẹ inú Bíbélì:

    • Ais 44:9-20—Jèhófà sọ nípasẹ̀ wòlíì Àìsáyà pé kò bọ́gbọ́n mu rárá kéèyàn máa jọ́sìn òrìṣà

    • Da 3:1-30—Àwọn ọ̀dọ́ Hébérù mẹ́ta tó jẹ́ ọ̀rẹ́ wòlíì Dáníẹ́lì gbà kí wọ́n ju àwọn sínú iná ìléru, dípò tí wọ́n á fi jọ́sìn òrìṣà