Lọ wo ohun tó wà nínú rẹ̀

Lọ wo àwọn ohun tó wà

Ìṣekúṣe

Ìṣekúṣe

Ìwà àìnítìjú; ìwà àìmọ́; àgbèrè

Ẹk 20:13-17; Mk 7:21-23; 1Kọ 6:9, 10, 18; Ga 5:19, 21; Ef 5:5; 1Pe 4:3

Tún wo Le 20:10; Owe 6:32; Ro 13:13; Ef 4:19; 5:3; 2Pe 2:2, 7, 8, 18, 19

  • Àpẹẹrẹ inú Bíbélì:

    • Jẹ 39:7-12—Léraléra ni ìyàwó Pọ́tífárì ń rọ Jósẹ́fù pé kó wá bá òun sùn, àmọ́ Jósẹ́fù ò gbà fún un rárá

    • 2Sa 12:7-14—Lẹ́yìn tí Ọba Dáfídì ṣèṣekúṣe pẹ̀lú Bátí-ṣébà, ọ̀pọ̀ ọdún ni ìdílé ẹ̀ fi jìyà torí ohun tó ṣe náà