Lọ wo ohun tó wà nínú rẹ̀

Lọ wo àwọn ohun tó wà

Ojúsàájú

Ojúsàájú

Owe 28:21; Ro 2:11; Jem 3:17

Tún wo Le 19:15; 2Kr 19:6, 7; 1Pe 1:17

  • Àpẹẹrẹ inú Bíbélì:

    • 1Sa 16:4-13—Nígbà tí wòlíì Sámúẹ́lì fẹ́ yan ẹni tó máa jẹ́ ọba Ísírẹ́lì lẹ́yìn Sọ́ọ̀lù, Jèhófà sọ fún un pé kó má wo ìrísí nìkan