Lọ wo ohun tó wà nínú rẹ̀

Lọ wo àwọn ohun tó wà

Àwọn Àna

Àwọn Àna

Tí ọkùnrin àti obìnrin kan bá ṣègbéyàwó, kí nìdí tí kò fi yẹ káwọn òbí àtàwọn àna máa tojú bọ ohun tó ń lọ nínú ìdílé wọn?

Jẹ 2:24; Mt 19:4, 5

Tún wo Sm 34:14; Mt 5:9; Ro 12:18; 14:10-13

  • Àpẹẹrẹ inú Bíbélì:

    • Ẹk 18:1-27—Mósè àti Jẹ́tírò tó jẹ́ bàbá ìyàwó ẹ̀ bọ̀wọ̀ fún ara wọn