Lọ wo ohun tó wà nínú rẹ̀

Lọ wo àwọn ohun tó wà

Owú

Owú

Owú Burúkú

Owe 14:30; 1Kọ 13:4

  • Àpẹẹrẹ inú Bíbélì:

    • Jẹ 4:3-8—Kéènì jowú Ébẹ́lì, ó wá bẹ̀rẹ̀ sí í kórìíra rẹ̀, ìyẹn sì mú kó pa á nígbà tó yá

    • Jẹ 37:9-11—Àwọn ẹ̀gbọ́n Jósẹ́fù jowú ẹ̀

    • 1Sa 18:6-9—Ọba Sọ́ọ̀lù ń jowú Dáfídì, kò sì fọkàn tán an mọ́

Owú; ìlara

Kí ló lè ràn wá lọ́wọ́ tá ò fi ní máa jowú?