Lọ wo ohun tó wà nínú rẹ̀

Lọ wo àwọn ohun tó wà

Ayọ̀

Ayọ̀

Báwo la ṣe mọ̀ pé Ọlọ́run aláyọ̀ ni Jèhófà?

Àwọn nǹkan wo ló lè mú ká máa láyọ̀?

Sm 100:2; Onw 8:15; Ais 65:14, 18; Flp 4:1, 4

Tún wo Sm 64:10; Ais 61:10; Mt 5:11, 12

  • Àpẹẹrẹ inú Bíbélì:

    • Sm 16:7-9, 11—Ọba Dáfídì ní àjọṣe tó dáa pẹ̀lú Jèhófà, ìyẹn sì mú kó láyọ̀ tó pọ̀

    • Heb 12:1-3—Àpọ́sítélì Pọ́ọ̀lù sọ pé tá a bá tiẹ̀ níṣòro tó le gan-an, a ṣì lè máa láyọ̀ bíi ti Jésù tá a bá ń ronú lórí ìrètí tá a ní