Lọ wo ohun tó wà nínú rẹ̀

Lọ wo àwọn ohun tó wà

Àlàáfíà

Àlàáfíà

Báwo la ṣe mọ̀ pé Jèhófà fẹ́ràn àlàáfíà?

Àwọn nǹkan wo la lè ṣe tá a bá fẹ́ nífọ̀kànbalẹ̀, tá a sì fẹ́ kí àlàáfíà wà láàárín àwa àtàwọn èèyàn?

Sm 119:165; Ais 48:17, 18; Ro 12:17-21; Flp 4:6-9

Tún wo Jo 16:33; Ef 6:14, 15; Kol 3:15

  • Àpẹẹrẹ inú Bíbélì:

    • Jẹ 32:9-21; 33:1-4—Jékọ́bù ṣiṣẹ́ kára, ó sì ṣe gbogbo ohun tó lè ṣe kí àlàáfíà lè wà láàárín òun àti Ísọ̀ arákùnrin ẹ̀

    • Mt 5:23-26—Jésù sọ ìdí tó fi ṣe pàtàkì ká máa wá àlàáfíà, ó sì sọ àǹfààní tá a máa rí tá a bá ń ṣe bẹ́ẹ̀