Lọ wo ohun tó wà nínú rẹ̀

Lọ wo àwọn ohun tó wà

Àwòrán Ìṣekúṣe

Àwòrán Ìṣekúṣe

Job 31:1; Sm 101:2, 3; Mt 5:27-30; Kol 3:5

Tún wo 1Kọ 6:18; Ef 4:17-19

  • Àpẹẹrẹ inú Bíbélì:

    • Jẹ 6:1, 2; Jud 6—Àwọn áńgẹ́lì kan tẹjú mọ́ àwọn obìnrin débi tó fi wù wọ́n láti bá wọn ṣèṣekúṣe, ìyẹn sì mú kí àjọṣe wọn pẹ̀lú Jèhófà bà jẹ́

    • 2Sa 11:2-4—Torí pé Ọba Dáfídì tẹjú mọ́ Bátí-ṣébà nígba tó ń wẹ̀, ó bá a ṣèṣekúṣe, ó sì tún pa ọkọ ẹ̀ nígbà tó yá