Lọ wo ohun tó wà nínú rẹ̀

Lọ wo àwọn ohun tó wà

Ìgbéraga

Ìgbéraga

Ìgbéraga; ìfọ́nnu

Sm 138:6; Owe 16:5, 18; Jem 4:6, 16

Tún wo Owe 21:4

  • Àpẹẹrẹ inú Bíbélì:

    • Ẹst 5:9-14; 7:9, 10—Torí pé agbéraga ni Hámánì, inú bí i nígbà tí Módékáì kọ̀ láti tẹrí ba fún un, ìgbéraga yẹn náà ló sì pa dà yọrí sí ikú ẹ̀

    • Isk 28:11-15, 17, 19—Ọba Tírè gbára lé ọrọ̀ àti agbára tó ní, torí náà ó di agbéraga, ó sì pa run nígbẹ̀yìngbẹ́yín