Lọ wo ohun tó wà nínú rẹ̀

Lọ wo àwọn ohun tó wà

Olè

Olè

Ẹk 20:15; Ef 4:28; 1Pe 4:15

Tún wo Jer 2:26; Mt 19:17, 18

  • Àpẹẹrẹ inú Bíbélì:

    • Isk 33:14-16—Jèhófà ṣèlérí pé òun máa dárí ji àwọn ẹni burúkú, títí kan àwọn olè tó ronú pìwà dà, tó sì yíwà pa dà

    • Jo 12:4-6—Olè ni Júdásì Ìsìkáríọ́tù, ó tún di ọ̀dàlẹ̀ nígbà tó yá