Lọ wo ohun tó wà nínú rẹ̀

Lọ wo àwọn ohun tó wà

Ogun

Ogun

Kí nìdí tí kò fi yẹ kó yà wá lẹ́nu pé ogun ń jà lọ́pọ̀ ibi lásìkò tá a wà yìí?

Mt 24:3, 4, 7, 8

  • Àpẹẹrẹ inú Bíbélì:

    • Da 11:40—Jèhófà mú kí wòlíì Dáníẹ́lì rí ìran kan nípa àwọn ọjọ́ ìkẹyìn tá a wà yìí, nínú ìran náà, ó rí i pé àwọn orílẹ̀-èdè alágbára méjì ń bára wọn díje, wọ́n sì ń figa gbága

    • Ifi 6:1-4—Àpọ́sítélì Jòhánù rí ẹṣin aláwọ̀ iná kan tó ń ṣàpẹẹrẹ ogun, ẹni tó jókòó sórí ẹṣin náà sì ní àṣẹ “láti mú àlàáfíà kúrò ní ayé”

Kí ni Jèhófà máa ṣe sí ogun?

Kí nìdí táwa Kristẹni kì í fi í dá sí ogun?

Kí nìdí tí Jèhófà àti Jésù fi máa jagun, àwọn wo ni wọ́n sì máa bá jagun?

Irú ogun wo làwọn Kristẹni tòótọ́ máa ń jà?

Báwo làwa Kristẹni ṣe lè yẹra fún àwọn ìwà tó lè yọrí sí ogun, irú bíi kéèyàn jẹ́ oníjà tàbí kó máa gbẹ̀san?