Lọ wo ohun tó wà nínú rẹ̀

Lọ wo àwọn ohun tó wà

ORIN 157

Àlàáfíà Ayérayé!

Àlàáfíà Ayérayé!

(Sáàmù 29:11)

  1. 1. Ní inú ayé yìí,

    Kò sí àlàáfíà,

    Àmọ́, ọkàn tiwa balẹ̀.

    A mọ̀ pé láìpẹ́,

    Ayé tuntun máa dé

    A ó sì máa fayọ̀

    kọrin pé:

    (ÈGBÈ)

    A fọpẹ́ fún Baba,

    Àlàáfíà dé!

    Ìtura dé sáyé!

    Ìbẹ̀rù kò sí mọ́,

    Ìbànújẹ́ tán

    Àlàáfíà

    ayérayé dé!

  2. 2. Tíjọba Ọlọ́run

    Bá gbàkóso

    Kò ní sógun, kò sọ́tẹ̀ mọ́.

    Gbogbo èèyàn máa

    Wà ní àlàáfíà.

    Kò ní síṣòro mọ́ láyé.

    (ÈGBÈ)

    A fọpẹ́ fún Baba,

    Àlàáfíà dé!

    Ìtura dé sáyé!

    Ìbẹ̀rù kò sí mọ́,

    Ìbànújẹ́ tán

    Àlàáfíà

    ayérayé dé!

    (ÈGBÈ)

    A fọpẹ́ fún Baba,

    Àlàáfíà dé!

    Ìtura dé sáyé!

    Ìbẹ̀rù kò sí mọ́,

    Ìbànújẹ́ tán

    Ayé tuntun ti dé!

    (ÈGBÈ)

    A fọpẹ́ fún Baba,

    Àlàáfíà dé!

    Ìtura dé sáyé!

    Ìbẹ̀rù kò sí mọ́,

    Ìbànújẹ́ tán

    Àlàáfíà

    ayérayé dé!

    Ó ti dé!